Isa 51:8 YCE

8 Nitori kòkoro yio jẹ wọn bi ẹ̀wu, idin yio si jẹ wọn bi irun agutan: ṣugbọn ododo mi yio wà titi lai, ati igbala mi lati iran de iran.

Ka pipe ipin Isa 51

Wo Isa 51:8 ni o tọ