Isa 54:15 YCE

15 Kiye si i, ni kikojọ nwọn o kó ara wọn jọ, ṣugbọn ki iṣe nipasẹ mi; ẹnikẹni ti o ba ditẹ si ọ yio ṣubu nitori rẹ.

Ka pipe ipin Isa 54

Wo Isa 54:15 ni o tọ