Isa 54:3 YCE

3 Nitori iwọ o ya si apa ọtún ati si apa osì, iru-ọmọ rẹ yio si jogun awọn keferi: nwọn o si mu ki awọn ilu ahoro wọnni di ibi gbigbe.

Ka pipe ipin Isa 54

Wo Isa 54:3 ni o tọ