Isa 60:21 YCE

21 Ati awọn enia rẹ, gbogbo wọn o jẹ olododo: nwọn o jogun ilẹ na titi lailai, ẹka gbigbin mi, iṣẹ ọwọ́ mi, ki a ba le yìn mi logo.

Ka pipe ipin Isa 60

Wo Isa 60:21 ni o tọ