Owe 11:18 YCE

18 Enia buburu nṣiṣẹ ère-ẹ̀tan; ṣugbọn ẹniti ngbin ododo ni ère otitọ wà fun.

Ka pipe ipin Owe 11

Wo Owe 11:18 ni o tọ