Owe 12:4 YCE

4 Obinrin oniwa-rere li ade ọkọ rẹ̀: ṣugbọn eyi ti ndojuti ni dabi ọyún ninu egungun rẹ̀.

Ka pipe ipin Owe 12

Wo Owe 12:4 ni o tọ