11 Nigbati a ba jẹ ẹlẹgàn ni ìya, a sọ òpe di ọlọgbọ́n: nigbati a ba si nkọ́ ọlọgbọ́n, on o ma ni ìmọ.
Ka pipe ipin Owe 21
Wo Owe 21:11 ni o tọ