Owe 28:18 YCE

18 Ẹnikẹni ti o ba nrin dẽde ni yio là: ṣugbọn ẹniti o nfi ayidayida rìn loju ọ̀na meji, yio ṣubu ninu ọkan ninu wọn.

Ka pipe ipin Owe 28

Wo Owe 28:18 ni o tọ