Owe 28:20 YCE

20 Olõtọ enia yio pọ̀ fun ibukún: ṣugbọn ẹniti o kanju ati là kì yio ṣe alaijiya.

Ka pipe ipin Owe 28

Wo Owe 28:20 ni o tọ