Owe 30:14 YCE

14 Iran kan wà, ehin ẹniti o dabi idà, erigi rẹ̀ dabi ọbẹ, lati jẹ talaka run kuro lori ilẹ, ati awọn alaini kuro ninu awọn enia.

Ka pipe ipin Owe 30

Wo Owe 30:14 ni o tọ