Owe 30:5 YCE

5 Gbogbo ọ̀rọ Oluwa jẹ́ otitọ: on li asà fun gbogbo awọn ti o gbẹkẹ wọn le e.

Ka pipe ipin Owe 30

Wo Owe 30:5 ni o tọ