1 Sámúẹ́lì 10:9 BMY

9 Bí Ṣọ́ọ̀lù ti yípadà láti fi Sámúẹ́lì sílẹ̀, Ọlọ́run yí ọkàn Ṣọ́ọ̀lù padà àti pé gbogbo àmì wọ̀nyí sì wá sí ìmúṣẹ ní ọjọ́ náà.

Ka pipe ipin 1 Sámúẹ́lì 10

Wo 1 Sámúẹ́lì 10:9 ni o tọ