1 Sámúẹ́lì 11:2 BMY

2 Ṣùgbọ́n Náhásì ará Ámónì sì wí fún un pé, “Nípa èyí ni èmi ó ò fi bá a yín ṣe ìpinnu, nípa yíyọ gbogbo ojú ọtún yín kúró, èmi o si fi yín se ẹlẹ́yà lójú gbogbo Ísírẹ́lì.”

Ka pipe ipin 1 Sámúẹ́lì 11

Wo 1 Sámúẹ́lì 11:2 ni o tọ