1 Sámúẹ́lì 11:1 BMY

1 Náhásì ará Ámónì gòkè lọ, ó sì dó ti Jabesi-Gílíádì, gbogbo ọkùnrin Jábésì sì wí fún Néhásì pé, “Bá wa ṣe ìpinnú, àwa yóò sì máa sìn ọ́.”

Ka pipe ipin 1 Sámúẹ́lì 11

Wo 1 Sámúẹ́lì 11:1 ni o tọ