19 Gbogbo àwọn ènìyàn sì wí fún Sámúẹ́lì pé, “Gbàdúrà sí Olúwa Ọlọ́run rẹ fún àwọn ìránṣẹ́ rẹ kí a má ba à kú, nítorí tí àwa ti fi búburú yìí kún ẹ̀ṣẹ̀ wa ní bí béèrè fún ọba.”
Ka pipe ipin 1 Sámúẹ́lì 12
Wo 1 Sámúẹ́lì 12:19 ni o tọ