20 Sámúẹ́lì sì dá wọn lóhùn pé, “Ẹ má bẹ̀rù, ẹ ti ṣe gbogbo búburú yìí; ṣíbẹ̀ ẹ má ṣe yípadà kúrò lọ́dọ̀ Olúwa, ṣùgbọ́n ẹ fi gbogbo àyà yín sin Olúwa.
Ka pipe ipin 1 Sámúẹ́lì 12
Wo 1 Sámúẹ́lì 12:20 ni o tọ