2 Nísinsìn yìí ẹ ti ní ọba bí olórí yín. Bí ó ṣe tèmi, èmi ti di arúgbó, mo sì ti hewú, àwọn ọmọ mi sì ń bẹ níhìn yìí pẹ̀lú yín. Èmi ti ń ṣe olórí yín láti ìgbà èwe mi wá títí di òní yìí.
Ka pipe ipin 1 Sámúẹ́lì 12
Wo 1 Sámúẹ́lì 12:2 ni o tọ