1 Sámúẹ́lì 12:3 BMY

3 Èmi dúró níhìn yìí, ẹ jẹ́rìí sí mi níwájú Olúwa àti níwájú ẹni àmì òróró rẹ̀. Màlúù ta ni mo gbà rí? Kẹ́tẹ́kẹ́tẹ́ ta ni mo gbà rí? Ta ni mo rẹ́ jẹ rí? Ọwọ́ ta ni mo ti gba owó àbẹ̀tẹ́lẹ̀ kan rí láti fi ti ara mi lójú? Bí mo bá ti ṣe ìkankan nínú ohun wọ̀nyí, èmi yóò sì san án padà fún un yín.”

Ka pipe ipin 1 Sámúẹ́lì 12

Wo 1 Sámúẹ́lì 12:3 ni o tọ