19 A kò sì rí alágbẹ̀dẹ kan ní gbogbo ilẹ̀ Ísírẹ́lì, nítorí tí àwọn Fílístínì wí pé, “Bí kò ṣe bẹ́ẹ̀ àwọn Hébérù yóò rọ idà tàbí ọ̀kọ̀!”
Ka pipe ipin 1 Sámúẹ́lì 13
Wo 1 Sámúẹ́lì 13:19 ni o tọ