1 Sámúẹ́lì 13:20 BMY

20 Bẹ́ẹ̀ ni gbogbo Ísírẹ́lì tọ àwọn Fílístínì lọ láti pọ́n dòjé wọn, ọ̀kọ̀, àáké àti ọ̀ṣọ̀ wọn.

Ka pipe ipin 1 Sámúẹ́lì 13

Wo 1 Sámúẹ́lì 13:20 ni o tọ