1 Sámúẹ́lì 13:21 BMY

21 Iye tí wọ́n fi pọ́n dòjé àti ọ̀kọ̀ jẹ́ ọwọ́ méjì nínú ìdásímẹ́ta ṣékélì, àti ìdásímẹ́ta ṣékélì fún pípọ́n ọ̀yà-irin tí ilẹ̀, àáké àti irin ọ̀pá olùṣọ́ màlúù.

Ka pipe ipin 1 Sámúẹ́lì 13

Wo 1 Sámúẹ́lì 13:21 ni o tọ