1 Sámúẹ́lì 13:22 BMY

22 Bẹ́ẹ̀ ni ọjọ́ ìjà ẹnìkankan nínú àwọn ọmọ ogun tí ó wà pẹ̀lú Ṣọ́ọ̀lù àti Jónátanì kò sì ní idà, tàbí ọ̀kọ̀ ní ọwọ́; àfi Ṣọ́ọ̀lù àti ọmọ rẹ̀ Jónátanì ni wọ́n ni wọ́n.

Ka pipe ipin 1 Sámúẹ́lì 13

Wo 1 Sámúẹ́lì 13:22 ni o tọ