1 Sámúẹ́lì 13:3 BMY

3 Jónátánì sì kọlu ẹgbẹ́ ogun àwọn Fílístínì ní Gébà, Fílístínì sì gbọ́ èyí. Nígbà náà ni Ṣọ́ọ̀lù fọn ìpè yí gbogbo ilẹ̀ náà ká, ó sì wí pé, “Jẹ́ kí àwọn Hébérù gbọ́!”

Ka pipe ipin 1 Sámúẹ́lì 13

Wo 1 Sámúẹ́lì 13:3 ni o tọ