1 Sámúẹ́lì 13:4 BMY

4 Bẹ́ẹ̀ ni gbogbo Ísírẹ́lì sì gbọ́ ìròyìn pé, “Ṣọ́ọ̀lù ti kọlu ẹgbẹ́ ogun àwọn Fílístínì, Ísírẹ́lì sì di òórùn búburú fún àwọn Fílístínì.” Àwọn ènìyàn náà sì péjọ láti dara pọ̀ mọ́ Ṣọ́ọ̀lù ní Gílígálì.

Ka pipe ipin 1 Sámúẹ́lì 13

Wo 1 Sámúẹ́lì 13:4 ni o tọ