1 Sámúẹ́lì 14:49 BMY

49 Àwọn ọmọ Sọ́ọ̀lù sì ni Jónátánì, Ísúì àti Málíkísúà. Orúkọ ọmọbìnrin rẹ̀ àgbà sì ni Mérábù àti orúkọ ọmọbìnrin rẹ̀ kékeré ni Míkálì.

Ka pipe ipin 1 Sámúẹ́lì 14

Wo 1 Sámúẹ́lì 14:49 ni o tọ