1 Sámúẹ́lì 14:50 BMY

50 Orúkọ ìyàwó rẹ̀ ní Áhínóámù ọmọbìnrin Áhímásì. Orúkọ olórí ogun rẹ̀ ni Ábínérì ọmọ Nérì arákùnrin baba Sọ́ọ̀lù.

Ka pipe ipin 1 Sámúẹ́lì 14

Wo 1 Sámúẹ́lì 14:50 ni o tọ