1 Sámúẹ́lì 16:10 BMY

10 Jésè jẹ́ kí àwọn ọmọ rẹ̀ méje rìn kọjá ní iwájú Sámúẹ́lì ṣùgbọ́n Sámúẹ́lì sọ fún un pé, “Olúwa kò yan àwọn wọ̀nyí.”

Ka pipe ipin 1 Sámúẹ́lì 16

Wo 1 Sámúẹ́lì 16:10 ni o tọ