1 Sámúẹ́lì 16:9 BMY

9 Jésè sì jẹ́ kí Sámà rìn kọjá ní iwájú Sámúẹ́lì, ṣùgbọ́n Sámúẹ́lì wí pé, “Olúwa kò yan ẹni yìí náà.”

Ka pipe ipin 1 Sámúẹ́lì 16

Wo 1 Sámúẹ́lì 16:9 ni o tọ