1 Sámúẹ́lì 2:1 BMY

1 Hánà sì gbàdúrà pé:“Ọkàn mi yọ̀ sí Olúwa;Ìwọ agbára mi ni a sì gbé sókè sí Olúwa.Ẹnu mi sì gbòòrò lórí àwọn ọ̀ta mi,nítorí ti èmi yọ̀ ni igbala rẹ̀

Ka pipe ipin 1 Sámúẹ́lì 2

Wo 1 Sámúẹ́lì 2:1 ni o tọ