1 Sámúẹ́lì 2:26 BMY

26 Ọmọ náà Sámúẹ́lì ń dàgbà, ó sì rí ojúrere lọ́dọ̀ Olúwa, àti ènìyàn pẹ̀lú.

Ka pipe ipin 1 Sámúẹ́lì 2

Wo 1 Sámúẹ́lì 2:26 ni o tọ