1 Sámúẹ́lì 27:11 BMY

11 Dáfídì kò sì dá ọkùnrin tàbí obìnrin sí láàyè, láti mú ìròyìn wá sí Gátì, wí pé, “Ki wọn máa bá à sọ ọ̀rọ̀ wa nibẹ̀, pé, ‘Báyìí ni Dáfídì ṣe’ ” Àti bẹ́ẹ̀ ni iṣe rẹ̀ yóò sì rí ni gbogbo ọjọ́ ti yóò fí jókòó ni ìlú àwọn Fílístínì.

Ka pipe ipin 1 Sámúẹ́lì 27

Wo 1 Sámúẹ́lì 27:11 ni o tọ