1 Sámúẹ́lì 27:10 BMY

10 Ákíṣì sì bi í pé, “Níbo ni ẹ̀yin gbé rìn sí lónìí?” Dáfídì sì dáhùn pé, “Síhà gúsù ti Júdà ni, tàbí Síhà gúsù ti Jérámélì,” tàbí “Síhà gúsù ti àwọn ará Kénì.”

Ka pipe ipin 1 Sámúẹ́lì 27

Wo 1 Sámúẹ́lì 27:10 ni o tọ