1 Sámúẹ́lì 27:9 BMY

9 Dáfídì sì kọlu ilẹ̀ náà kò sì fi ọkùnrin tàbí obìnrin sílẹ̀ láàyè, ó sì kó àgùntàn, àti màlúù, àti kẹ́tẹ́kẹ́tẹ́, àti ràkúnmí, àti aṣọ, ó sì yípadà ó tọ Ákíṣì wá.

Ka pipe ipin 1 Sámúẹ́lì 27

Wo 1 Sámúẹ́lì 27:9 ni o tọ