1 Sámúẹ́lì 29:2 BMY

2 Àwọn ìjòyé Fílístínì sì kọjá ní ọ̀rọ̀ọ̀rún àti lẹ́gbẹgbẹ̀rún; Dáfídì àti àwọn ọmọkùnrin rẹ̀ pẹ̀lú Ákíṣì sì kẹ́yìn.

Ka pipe ipin 1 Sámúẹ́lì 29

Wo 1 Sámúẹ́lì 29:2 ni o tọ