1 Sámúẹ́lì 29:3 BMY

3 Àwọn ìjòyé Fílístínì sì béèrè wí pé, “Kín ni àwọn Hébérù ń ṣe nìhìn-ín yìí?”Ákíṣì sì wí fún àwọn ìjòyè Fílístínì pé “Dáfídì kọ yìí, ìránṣẹ́ Ṣọ́ọ̀lù ọba Ísírẹ́lì, tí ó wà lọ́dọ̀ mi láti ọjọ́ wọ̀nyí tàbí láti ọdún wọ̀nyí, èmi kò ì tì í rí àṣìṣe kan ni ọwọ́ rẹ̀ lati ọjọ́ tí ó ti dé ọ̀dọ̀ mi títí di òní yìí.”

Ka pipe ipin 1 Sámúẹ́lì 29

Wo 1 Sámúẹ́lì 29:3 ni o tọ