1 Sámúẹ́lì 29:4 BMY

4 Àwọn ìjòyé Fílístínì sì bínú sí i; àwọn ìjòyé Fílístínì sì wí fún un pé, “Jẹ́ kí ọkùnrin yìí padà kí ó sì lọ sí ipó rẹ̀ tí ó fi fún un, kí ó má sì jẹ́ kí ó bá wa sọ̀kalẹ̀ lọ sí ogun, kí ó má ba à jásí ọ̀ta fún wa ni ogun; Kín ni òun ó fi ba olúwa rẹ̀ làjà, orí àwọn ènìyàn wọ̀nyí kọ́?

Ka pipe ipin 1 Sámúẹ́lì 29

Wo 1 Sámúẹ́lì 29:4 ni o tọ