1 Sámúẹ́lì 29:5 BMY

5 Ṣé èyí ni Dáfídì ti wọn torí rẹ̀ gberin ara wọn nínú ìjọ wí pé,“ ‘Ṣọ́ọ̀lù pa ẹgbẹgbẹrun rẹ̀,Dáfídì si pa ẹgbẹgbàárun tirẹ́.’ ”

Ka pipe ipin 1 Sámúẹ́lì 29

Wo 1 Sámúẹ́lì 29:5 ni o tọ