1 Sámúẹ́lì 31:5 BMY

5 Nígbà tí ẹni tí ó ru ìhámọ́ra rẹ̀ si ríi pé Ṣọ́ọ̀lù kú, òun náà sì fi idà rẹ̀ pá ara rẹ̀, ó sì kú pẹ̀lú rẹ̀.

Ka pipe ipin 1 Sámúẹ́lì 31

Wo 1 Sámúẹ́lì 31:5 ni o tọ