1 Sámúẹ́lì 31:6 BMY

6 Ṣọ́ọ̀lù sì kú, àti àwọn ọmọ rẹ̀ mẹ́ta, àti ẹni tí ó ru ìhámọ́ra rẹ̀, àti gbogbo àwọn ọmọkùrin rẹ̀ ní ọjọ́ kan náà.

Ka pipe ipin 1 Sámúẹ́lì 31

Wo 1 Sámúẹ́lì 31:6 ni o tọ