1 Sámúẹ́lì 31:8 BMY

8 Ní ọjọ́ kejì, nígbà tí àwọn Fílístínì dé láti bọ́ nǹkán tí ń bẹ lára àwọn tí ó kù, wọ́n sì rí pé, Ṣọ́ọ̀lù àti àwọn ọmọ rẹ̀ mẹ́ta ṣubú ni òkè Gílíbóà.

Ka pipe ipin 1 Sámúẹ́lì 31

Wo 1 Sámúẹ́lì 31:8 ni o tọ