1 Sámúẹ́lì 31:9 BMY

9 Wọ́n sì gé orí rẹ̀, wọ́n sì bọ ìhámọ́ra rẹ̀, wọ́n sì ránṣẹ́ lọ ilẹ̀ Fílístínì káàkiri, láti máa sọ ọ́ nígbángba ni ilé òrìṣà wọn, àti láàrin àwọn ènìyàn.

Ka pipe ipin 1 Sámúẹ́lì 31

Wo 1 Sámúẹ́lì 31:9 ni o tọ