1 Sámúẹ́lì 5:11 BMY

11 Nígbà náà ni wọ́n pe gbogbo àwọn olórí àwọn Fílístínì jọ wọ́n sì wí pé, “Ẹ gbé àpótí ẹ̀rí Ọlọ́run àwọn Ísírẹ́lì lọ: ẹ jẹ́ kí ó padà sí àyè rẹ̀, bí bẹ́ẹ̀ kọ́ yóò pa wá àti àwọn ènìyàn wa.” Ikú ti mú jìnnìjìnnì bá àwọn ará ìlú: ọwọ́ Ọlọ́run sì wúwo lára wọn.

Ka pipe ipin 1 Sámúẹ́lì 5

Wo 1 Sámúẹ́lì 5:11 ni o tọ