1 Sámúẹ́lì 5:10 BMY

10 Wọ́n gbé àpótí ẹ̀rí Ọlọ́run lọ sí Ékírónì.Bí àpótí ẹ̀rí Ọlọ́run ṣe wọ Ékírónì, àwọn ará Ékírónì fi igbe ta pé, “Wọ́n ti gbé àpótí ẹ̀rí Ọlọ́run Ísírẹ́lì tọ̀ wá wá láti pa wá àti àwọn ènìyàn wa.”

Ka pipe ipin 1 Sámúẹ́lì 5

Wo 1 Sámúẹ́lì 5:10 ni o tọ