1 Sámúẹ́lì 7:2 BMY

2 Ó sì jẹ́ ní ìgbà pípẹ́, ogún ọdún ni àpótí ẹ̀rí Olúwa fi wà ní Kiriati Jéárímù. Gbogbo ilé Ísírẹ́lì ṣọ̀fọ̀ wọ́n sì pohùn réré ẹkún sí Olúwa.

Ka pipe ipin 1 Sámúẹ́lì 7

Wo 1 Sámúẹ́lì 7:2 ni o tọ