1 Sámúẹ́lì 8:12 BMY

12 Yóò yan díẹ̀ láti jẹ́ olórí ẹgbẹ̀rún àti olórí àádọ́ta àti àwọn mìíràn. Yóò yan wọ́n láti máa tulẹ̀ oko rẹ̀ àti láti máa kórè rẹ̀ àti àwọn mìíràn láti máa ṣe ohun èlò ogun àti ohun èlò kẹ̀kẹ́ ogun rẹ̀.

Ka pipe ipin 1 Sámúẹ́lì 8

Wo 1 Sámúẹ́lì 8:12 ni o tọ