1 Sámúẹ́lì 8:13 BMY

13 Yóò mú àwọn ọmọbìnrin yín láti máa ṣe olùṣe ìkunra olóòórùn dídùn àti láti máa ṣe àṣè àti láti máa ṣe àkàrà.

Ka pipe ipin 1 Sámúẹ́lì 8

Wo 1 Sámúẹ́lì 8:13 ni o tọ