1 Sámúẹ́lì 8:20 BMY

20 Nígbà náà àwa yóò dàbí gbogbo àwọn orílẹ̀ èdè mìíràn, pẹ̀lú ọba láti darí i wa àti láti jáde lọ níwájú wa láti ja ogun wa.”

Ka pipe ipin 1 Sámúẹ́lì 8

Wo 1 Sámúẹ́lì 8:20 ni o tọ