Jẹnẹsisi 1:12 BM

12 Ilẹ̀ bá hu koríko jáde, oríṣìíríṣìí ohun ọ̀gbìn ati ewéko tí ń so ati oríṣìíríṣìí igi eléso tí ó ní irúgbìn ninu. Ọlọrun wò wọ́n, ó sì rí i pé wọ́n dára.

Ka pipe ipin Jẹnẹsisi 1

Wo Jẹnẹsisi 1:12 ni o tọ