Jẹnẹsisi 1:14 BM

14 Ọlọrun pàṣẹ pé kí àwọn ìmọ́lẹ̀ wà ní ojú ọ̀run, láti fi ààlà sí ààrin ọ̀sán ati òru, kí wọ́n wà láti jẹ́ àmì, ati láti máa fi àkókò àjọ̀dún, ọjọ́, ati ọdún hàn,

Ka pipe ipin Jẹnẹsisi 1

Wo Jẹnẹsisi 1:14 ni o tọ