Jẹnẹsisi 1:18 BM

18 láti máa jọba lórí ọ̀sán ati òru, ati láti fi ààlà sí ààrin ìmọ́lẹ̀ ati òkùnkùn. Ọlọrun wò wọ́n, ó sì rí i pé wọ́n dára.

Ka pipe ipin Jẹnẹsisi 1

Wo Jẹnẹsisi 1:18 ni o tọ